Yoruba |
English Translation |
---|---|
Ódòwúrọ̀.
Kí a sùn-ún ré. Kí ángẹ́lì olúwa ṣọ́ gbogbo wa |
Until morning comes again.
I hope we all sleep well. May the angel of the Lord keep us safe |
Ódòwúrọ̀.
Kí a sùn-ún ré. Kí ángẹ́lì olúwa ṣọ́ gbogbo wa |
Until morning comes again.
I hope we all sleep well. May the angel of the Lord keep us safe |
Láyọ̀ , Láyọ̀, Là ń lọ́ lé , Là ń lọ́ lé, Là ń lọ́ lé | Joyfully, Joyfully, we go home, we go home, we go home |
Láyọ̀ , Láyọ̀, Là ń lọ́ lé | Joyfully, Joyfully, we go home, |
K’olúwa ṣọ́ wa pọ̀ | May God keep us all. |